Home Local News MERANDA LA FÉ, ÀWON ASÒFIN ÈKÓ FOHÙN SÓKÈ, BÍ DSS SE YABO...

MERANDA LA FÉ, ÀWON ASÒFIN ÈKÓ FOHÙN SÓKÈ, BÍ DSS SE YABO ILÉ ASÒFIN

468
0


Deborah Gandonu Ochaba


Ile igbimo asofin ipinle Eko benuatelu bi awon Eso abo DSS ti won dira,bi eni lo soju Ogun,se yabo Ile igbimo asofin naa Loni,lasiko ipade awon asofin naa

Awon asofin naa to ka si pe igbese awon Eso abo DSS naa,ni lo idasi ni pajawiri, Toripe bi won yabo Ile asofin ipinle Eko Loni ,lati dabaru ijoko awon asofin naa Lodi sofin,o si je ohun to ta ko Eto isejoba awarawa

Saaju nibi ijoko awon asofin naa,ni akowe agba Ile igbimo asofin naa ti ka iwe ti Ile Ejo Fi sowo si Ile asofin naa seti gbo gbogbo awon asofin to wa nibi ipade naa,pe,Ejo ti Olori tele Ile asofin naa ti won yo nipo ,hon Mudashiru obasa ,pe tako igbese awon asofin naa nile ejo ,si wa lenu agbeyewo,eyi ni won si nji roro le lori ki awon Eso abo DSS to bere sini ja fita-fita lati le ribi wo ibi ijoko ipade awon asofin naa.

Awon asofin ipinle Eko ti ke si Ajo Eso abo DSS , pe ki won salaye ohun to sokunfa igbe