Home Local News
1077
0

OBASA SAJOYO PELU AYA AARE ORILEEDE YII, SENATOR OLUREMI TINUBU ,OON,CON,TO PE ENI ODUN MARUNDINLADORIN,O SI SAPEJUWE ETO IRETI OTUN BI IGBESE TO N LA IPA RERE LAARIN ILU


DEBORAH OCHABA

Olori ile igbimo asofin ipinle Eko,Rt hon Mudashiru Ajayi obasa ki Aya Aare Orileede yii, Senator Oluremi Tinubu OON,CON, ku orire ojo ibi re,Loni to pe eni odun marundinladorin,loke eepe.

O sapejuwe Aaya re bi Iya rere,to ti yonda ara re Lati ma se okanojokan Eto,ti yoo mayederun fun araalu ati orileede Nigeria lapapo,ati Bo se yonda ara re fun itesiwaju rere eto isejoba orileede.

Oro yii,jeyo ninu iwe ti Akowe Iroyin,Rt hon Mudashiru Obasa, ogbeni Dave Agboola fisita Lati Sami ayeye ojo ibi aya Aare.

Rt hon Mudashiru obasa sope Ipa rere ti Aya Aare orileede tiko ninu igbe aye araalu,paapa awon odo,kiise keremi, toripe okanojokan Eto lo ngunle Lati mu ki awon odo le wulo funrawon daduro lawujo.

Rt hon Obasa gbadura pe ki olorun fun Aaya Aare Senator Oluremi Tinubu ni emi gigun ati Alafia,kole tunbo satileyin oko re,mu erongba ireti isodotun ti isakoso akoko yii ni fun araalu.