Home Local News ILE ASOFIN EKO TI GBE IGBESE ATI SAWARI AWON OHUN INI IJOBA...

ILE ASOFIN EKO TI GBE IGBESE ATI SAWARI AWON OHUN INI IJOBA IPINLE YII,LOJUNA ATI GBA PADA

124
0


DEBORAH OCHABA


Ile asofin eko,ti sefilole igbimo eleni mejo kan ti yoo tanpinpin awon ohun ini ijoba to wa lakosile,atawon eyi ti ko si lakosile,ti yoo si gba won pada fun ijoba.

Alaga igbimo naa,Hon Obafemi Saheed fidie mule pe sise ayewo awon ohun ini ijoba ati sise afihan pato ipo ti won wa,je ojuse ile-asofin naa.O toka si pe,eyi niise pelu sise ayewo inawo ijoba,titanpinpin bijoba ti n na owo araalu,ati riri daju wipe ijoba na owo ori ti won ngba lowo araalu lona toye.

Hon Femi Saheed salaye pe eto naa,yoo fun igbimo eleni mejo tile asofin eko sagbekale,laanfani lati fidi awon ohun ini ijoba to wa laarin ilu mule,wo ipo ti won wa,lasiko yii,ati lati mo boya awon ohun ini ijoba naa wulo fun awon eyan ipinle eko,bijoba se gbero.

O ro gbogbo awon adar